Jòhánù 3:35 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 35 Baba nífẹ̀ẹ́ Ọmọ,+ ó sì ti fi gbogbo nǹkan sí ìkáwọ́ rẹ̀.+