ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Nọ́ńbà 28:9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 9 “Àmọ́, ní ọjọ́ Sábáàtì,+ kí ọrẹ náà jẹ́ akọ ọ̀dọ́ àgùntàn méjì tó jẹ́ ọlọ́dún kan tí ara wọn dá ṣáṣá àti ìyẹ̀fun kíkúnná tó jẹ́ ìdá méjì nínú mẹ́wàá òṣùwọ̀n eéfà tí wọ́n pò mọ́ òróró láti fi ṣe ọrẹ ọkà, pẹ̀lú ọrẹ ohun mímu rẹ̀.

  • Jòhánù 7:22
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 22 Ìdí nìyí tí Mósè fi sọ pé kí ẹ máa dádọ̀dọ́*+—kì í ṣe pé ó wá látọ̀dọ̀ Mósè, àmọ́ ọ̀dọ̀ àwọn baba ńlá ló ti wá+—ẹ sì ń dádọ̀dọ́ ọkùnrin ní sábáàtì.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́