Lúùkù 1:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Láyé ìgbà Hẹ́rọ́dù,*+ ọba Jùdíà, àlùfáà kan wà tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Sekaráyà nínú ìpín Ábíjà.+ Ọ̀kan lára àwọn ọmọbìnrin Áárónì ni ìyàwó rẹ̀, Èlísábẹ́tì ni orúkọ rẹ̀.
5 Láyé ìgbà Hẹ́rọ́dù,*+ ọba Jùdíà, àlùfáà kan wà tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Sekaráyà nínú ìpín Ábíjà.+ Ọ̀kan lára àwọn ọmọbìnrin Áárónì ni ìyàwó rẹ̀, Èlísábẹ́tì ni orúkọ rẹ̀.