Máàkù 3:35 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 35 Ẹnikẹ́ni tó bá ń ṣe ìfẹ́ Ọlọ́run, ẹni yẹn ni arákùnrin mi, arábìnrin mi àti ìyá mi.”+ Lúùkù 8:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Ó dá wọn lóhùn pé: “Ìyá mi àti àwọn arákùnrin mi ni àwọn yìí tó ń gbọ́ ọ̀rọ̀ Ọlọ́run, tí wọ́n sì ń ṣe é.”+
21 Ó dá wọn lóhùn pé: “Ìyá mi àti àwọn arákùnrin mi ni àwọn yìí tó ń gbọ́ ọ̀rọ̀ Ọlọ́run, tí wọ́n sì ń ṣe é.”+