Mátíù 2:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 wọ́n sọ pé: “Ibo ni ọba àwọn Júù tí wọ́n bí wà?+ Torí a rí ìràwọ̀ rẹ̀ nígbà tí a wà ní Ìlà Oòrùn, a sì ti wá ká lè forí balẹ̀* fún un.”
2 wọ́n sọ pé: “Ibo ni ọba àwọn Júù tí wọ́n bí wà?+ Torí a rí ìràwọ̀ rẹ̀ nígbà tí a wà ní Ìlà Oòrùn, a sì ti wá ká lè forí balẹ̀* fún un.”