Máàkù 4:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Torí náà, àwọn yìí ni àwọn tó bọ́ sí etí ọ̀nà, níbi tí a gbin ọ̀rọ̀ náà sí; àmọ́ gbàrà tí wọ́n gbọ́ ọ, Sátánì wá,+ ó sì mú ọ̀rọ̀ tí a gbìn sínú wọn kúrò.+ Lúùkù 8:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Àwọn ti etí ọ̀nà ni àwọn tó gbọ́, tí Èṣù wá lẹ́yìn náà, tó sì mú ọ̀rọ̀ náà kúrò nínú ọkàn wọn, kí wọ́n má bàa gbà gbọ́, kí wọ́n sì rí ìgbàlà.+
15 Torí náà, àwọn yìí ni àwọn tó bọ́ sí etí ọ̀nà, níbi tí a gbin ọ̀rọ̀ náà sí; àmọ́ gbàrà tí wọ́n gbọ́ ọ, Sátánì wá,+ ó sì mú ọ̀rọ̀ tí a gbìn sínú wọn kúrò.+
12 Àwọn ti etí ọ̀nà ni àwọn tó gbọ́, tí Èṣù wá lẹ́yìn náà, tó sì mú ọ̀rọ̀ náà kúrò nínú ọkàn wọn, kí wọ́n má bàa gbà gbọ́, kí wọ́n sì rí ìgbàlà.+