Máàkù 4:33, 34 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 33 Ó fi ọ̀pọ̀ irú àwọn àpèjúwe+ yẹn bá wọn sọ̀rọ̀, débi tí wọ́n lè fetí sílẹ̀ dé. 34 Ní tòótọ́, kì í bá wọn sọ̀rọ̀ láìlo àpèjúwe, àmọ́ ó máa ń ṣàlàyé gbogbo nǹkan fún àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ láwọn nìkan.+
33 Ó fi ọ̀pọ̀ irú àwọn àpèjúwe+ yẹn bá wọn sọ̀rọ̀, débi tí wọ́n lè fetí sílẹ̀ dé. 34 Ní tòótọ́, kì í bá wọn sọ̀rọ̀ láìlo àpèjúwe, àmọ́ ó máa ń ṣàlàyé gbogbo nǹkan fún àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ láwọn nìkan.+