Jeremáyà 31:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 “Ohun tí Jèhófà sọ nìyí: ‘A gbọ́ ohùn kan ní Rámà,+ ìdárò àti ẹkún kíkorò: Réṣẹ́lì ń sunkún nítorí àwọn ọmọkùnrin* rẹ̀.+ Wọ́n tù ú nínú nítorí àwọn ọmọ rẹ̀, àmọ́ kò gbà,Torí pé wọn kò sí mọ́.’”+
15 “Ohun tí Jèhófà sọ nìyí: ‘A gbọ́ ohùn kan ní Rámà,+ ìdárò àti ẹkún kíkorò: Réṣẹ́lì ń sunkún nítorí àwọn ọmọkùnrin* rẹ̀.+ Wọ́n tù ú nínú nítorí àwọn ọmọ rẹ̀, àmọ́ kò gbà,Torí pé wọn kò sí mọ́.’”+