Máàkù 7:1, 2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Àwọn Farisí àti àwọn kan lára àwọn akọ̀wé òfin tí wọ́n wá láti Jerúsálẹ́mù kóra jọ yí i ká.+ 2 Wọ́n sì rí i tí àwọn kan lára àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ ń fi ọwọ́ àìmọ́ jẹun, ìyẹn ọwọ́ tí wọn ò wẹ̀.*
7 Àwọn Farisí àti àwọn kan lára àwọn akọ̀wé òfin tí wọ́n wá láti Jerúsálẹ́mù kóra jọ yí i ká.+ 2 Wọ́n sì rí i tí àwọn kan lára àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ ń fi ọwọ́ àìmọ́ jẹun, ìyẹn ọwọ́ tí wọn ò wẹ̀.*