-
Máàkù 7:28Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
28 Àmọ́ obìnrin náà dá a lóhùn pé: “Bẹ́ẹ̀ ni sà, síbẹ̀, àwọn ajá kéékèèké tó wà lábẹ́ tábìlì pàápàá, máa ń jẹ lára èérún tó já bọ́ lọ́wọ́ àwọn ọmọ kéékèèké.”
-