-
Máàkù 8:11Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
11 Àwọn Farisí wá bá a níbẹ̀, wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ sí í bá a jiyàn, wọ́n ní kó fún àwọn ní àmì kan láti ọ̀run, kí wọ́n lè dán an wò.+
-
-
Lúùkù 11:16Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
16 Kí àwọn míì sì lè dán an wò, wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí í sọ fún un pé kó fi àmì kan+ láti ọ̀run han àwọn.
-