Máàkù 8:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Torí náà, ẹ̀dùn ọkàn bá a gidigidi nínú ẹ̀mí rẹ̀, ó sì sọ pé: “Kí ló dé tí ìran yìí ń wá àmì?+ Lóòótọ́ ni mo sọ, a ò ní fún ìran yìí ní àmì kankan.”+
12 Torí náà, ẹ̀dùn ọkàn bá a gidigidi nínú ẹ̀mí rẹ̀, ó sì sọ pé: “Kí ló dé tí ìran yìí ń wá àmì?+ Lóòótọ́ ni mo sọ, a ò ní fún ìran yìí ní àmì kankan.”+