Jòhánù 1:42 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 42 ó sì mú un lọ sọ́dọ̀ Jésù. Nígbà tí Jésù wò ó, ó sọ pé: “Ìwọ ni Símónì,+ ọmọ Jòhánù; a ó máa pè ọ́ ní Kéfà” (tó túmọ̀ sí “Pétérù”).+
42 ó sì mú un lọ sọ́dọ̀ Jésù. Nígbà tí Jésù wò ó, ó sọ pé: “Ìwọ ni Símónì,+ ọmọ Jòhánù; a ó máa pè ọ́ ní Kéfà” (tó túmọ̀ sí “Pétérù”).+