Máàkù 8:33 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 33 Ló bá yíjú pa dà, ó wo àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀, ó sì bá Pétérù wí, ó ní: “Dẹ̀yìn lẹ́yìn mi,* Sátánì! torí èrò èèyàn lò ń rò, kì í ṣe ti Ọlọ́run.”+
33 Ló bá yíjú pa dà, ó wo àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀, ó sì bá Pétérù wí, ó ní: “Dẹ̀yìn lẹ́yìn mi,* Sátánì! torí èrò èèyàn lò ń rò, kì í ṣe ti Ọlọ́run.”+