ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́kísódù 21:7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 7 “Tí ọkùnrin kan bá ta ọmọbìnrin rẹ̀ ní ẹrú, ọ̀gá rẹ̀ ò ní dá a sílẹ̀ bí wọ́n ti ń ṣe fún ọkùnrin tó jẹ́ ẹrú.

  • Léfítíkù 25:39
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 39 “‘Tí arákùnrin rẹ tó ń gbé nítòsí bá di aláìní, tó sì ní láti ta ara rẹ̀ fún ọ,+ má fipá mú un ṣe ẹrú.+

  • 2 Àwọn Ọba 4:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 4 Nígbà náà, ọ̀kan lára ìyàwó àwọn ọmọ wòlíì+ sunkún lọ bá Èlíṣà, ó ní: “Ìránṣẹ́ rẹ, ọkọ mi, ti kú, o sì mọ̀ pé gbogbo ọjọ́ ayé ìránṣẹ́ rẹ ni ó fi bẹ̀rù Jèhófà.+ Àmọ́ ní báyìí, ẹni tí a jẹ ní gbèsè ti wá láti kó àwọn ọmọ mi méjèèjì kó lè fi wọ́n ṣe ẹrú.”

  • Nehemáyà 5:8
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 8 Mo sọ fún wọn pé: “A ti ra àwọn Júù arákùnrin wa tí wọ́n tà fún àwọn orílẹ̀-èdè pa dà débi tí agbára wa gbé e dé; àmọ́, ṣé ẹ máa wá ta àwọn arákùnrin yín ni,+ ṣé ó yẹ ká tún rà wọ́n pa dà lọ́wọ́ yín ni?” Ni kẹ́kẹ́ bá pa mọ́ wọn lẹ́nu, wọn ò sì rí nǹkan kan sọ.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́