Àìsáyà 55:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Kí èèyàn burúkú fi ọ̀nà rẹ̀ sílẹ̀,+Kí ẹni ibi sì yí èrò rẹ̀ pa dà;Kó pa dà sọ́dọ̀ Jèhófà, ẹni tó máa ṣàánú rẹ̀,+Sọ́dọ̀ Ọlọ́run wa, torí ó máa dárí jini fàlàlà.*+ Mátíù 6:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 kí o sì dárí àwọn gbèsè wa jì wá, bí àwa náà ṣe dárí ji àwọn tó jẹ wá ní gbèsè.+ Mátíù 7:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 “Torí náà, gbogbo ohun tí ẹ bá fẹ́ kí àwọn èèyàn ṣe sí yín ni kí ẹ̀yin náà máa ṣe sí wọn.+ Ní tòótọ́, ohun tí Òfin àti àwọn Wòlíì túmọ̀ sí nìyí.+ Jémíìsì 2:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Torí ẹni tí kì í ṣàánú kò ní rí àánú gbà nígbà ìdájọ́.+ Àánú máa ń borí ìdájọ́.
7 Kí èèyàn burúkú fi ọ̀nà rẹ̀ sílẹ̀,+Kí ẹni ibi sì yí èrò rẹ̀ pa dà;Kó pa dà sọ́dọ̀ Jèhófà, ẹni tó máa ṣàánú rẹ̀,+Sọ́dọ̀ Ọlọ́run wa, torí ó máa dárí jini fàlàlà.*+
12 “Torí náà, gbogbo ohun tí ẹ bá fẹ́ kí àwọn èèyàn ṣe sí yín ni kí ẹ̀yin náà máa ṣe sí wọn.+ Ní tòótọ́, ohun tí Òfin àti àwọn Wòlíì túmọ̀ sí nìyí.+