1 Kọ́ríńtì 7:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ì bá wù mí kí gbogbo èèyàn dà bíi tèmi. Síbẹ̀, kálukú ló ní ẹ̀bùn tirẹ̀+ látọ̀dọ̀ Ọlọ́run, ọ̀kan lọ́nà yìí, òmíràn lọ́nà yẹn.
7 Ì bá wù mí kí gbogbo èèyàn dà bíi tèmi. Síbẹ̀, kálukú ló ní ẹ̀bùn tirẹ̀+ látọ̀dọ̀ Ọlọ́run, ọ̀kan lọ́nà yìí, òmíràn lọ́nà yẹn.