Mátíù 18:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 ó sì sọ pé: “Lóòótọ́ ni mo sọ fún yín, láìjẹ́ pé ẹ yí pa dà,* kí ẹ sì dà bí àwọn ọmọdé,+ ó dájú pé ẹ ò ní wọ Ìjọba ọ̀run.+ Máàkù 10:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Nígbà tí Jésù rí èyí, inú bí i, ó sì sọ fún wọn pé: “Ẹ jẹ́ kí àwọn ọmọdé wá sọ́dọ̀ mi; ẹ má sì dá wọn dúró, torí Ìjọba Ọlọ́run jẹ́ ti irú wọn.+ Lúùkù 18:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Ṣùgbọ́n, Jésù pe àwọn ọmọ kéékèèké náà wá sọ́dọ̀ ara rẹ̀, ó ní: “Ẹ jẹ́ kí àwọn ọmọdé wá sọ́dọ̀ mi, ẹ má sì dá wọn dúró, torí Ìjọba Ọlọ́run jẹ́ ti irú wọn.+
3 ó sì sọ pé: “Lóòótọ́ ni mo sọ fún yín, láìjẹ́ pé ẹ yí pa dà,* kí ẹ sì dà bí àwọn ọmọdé,+ ó dájú pé ẹ ò ní wọ Ìjọba ọ̀run.+
14 Nígbà tí Jésù rí èyí, inú bí i, ó sì sọ fún wọn pé: “Ẹ jẹ́ kí àwọn ọmọdé wá sọ́dọ̀ mi; ẹ má sì dá wọn dúró, torí Ìjọba Ọlọ́run jẹ́ ti irú wọn.+
16 Ṣùgbọ́n, Jésù pe àwọn ọmọ kéékèèké náà wá sọ́dọ̀ ara rẹ̀, ó ní: “Ẹ jẹ́ kí àwọn ọmọdé wá sọ́dọ̀ mi, ẹ má sì dá wọn dúró, torí Ìjọba Ọlọ́run jẹ́ ti irú wọn.+