ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Mátíù 17:22, 23
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 22 Ìgbà tí wọ́n kóra jọ sí Gálílì ni Jésù sọ fún wọn pé: “A máa fi Ọmọ èèyàn lé àwọn èèyàn lọ́wọ́,+ 23 wọ́n máa pa á, a sì máa jí i dìde ní ọjọ́ kẹta.”+ Inú wọn sì bà jẹ́ gidigidi.

  • Mátíù 28:6
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 6 Kò sí níbí, torí a ti jí i dìde, bó ṣe sọ gẹ́lẹ́.+ Ẹ wá wo ibi tí wọ́n tẹ́ ẹ sí.

  • Ìṣe 10:40
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 40 Ọlọ́run jí ẹni yìí dìde ní ọjọ́ kẹta,+ ó sì jẹ́ kó fara hàn kedere,*

  • 1 Kọ́ríńtì 15:4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 4 àti pé a sin ín,+ bẹ́ẹ̀ ni, pé a jí i dìde+ ní ọjọ́ kẹta+ bí Ìwé Mímọ́ ṣe sọ;+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́