Mátíù 26:39 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 39 Ó lọ síwájú díẹ̀, ó dojú bolẹ̀, ó sì gbàdúrà pé:+ “Baba mi, tó bá ṣeé ṣe, jẹ́ kí ife+ yìí ré mi kọjá. Síbẹ̀, kì í ṣe bí mo ṣe fẹ́, àmọ́ bí ìwọ ṣe fẹ́.”+ Máàkù 10:38 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 38 Àmọ́ Jésù sọ fún wọn pé: “Ẹ ò mọ ohun tí ẹ̀ ń béèrè. Ṣé ẹ lè mu ife tí mò ń mu àbí a lè batisí yín bí a ṣe ń batisí mi?”+ Máàkù 14:36 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 36 Ó sì sọ pé: “Ábà,* Bàbá,+ ohun gbogbo ṣeé ṣe fún ọ; mú ife yìí kúrò lórí mi. Síbẹ̀, kì í ṣe ohun tí èmi fẹ́, àmọ́ ohun tí ìwọ fẹ́.”+ Jòhánù 18:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Àmọ́ Jésù sọ fún Pétérù pé: “Fi idà náà sínú àkọ̀ rẹ̀.+ Ṣé kò yẹ kí n mu ife tí Baba fún mi ni?”+
39 Ó lọ síwájú díẹ̀, ó dojú bolẹ̀, ó sì gbàdúrà pé:+ “Baba mi, tó bá ṣeé ṣe, jẹ́ kí ife+ yìí ré mi kọjá. Síbẹ̀, kì í ṣe bí mo ṣe fẹ́, àmọ́ bí ìwọ ṣe fẹ́.”+
38 Àmọ́ Jésù sọ fún wọn pé: “Ẹ ò mọ ohun tí ẹ̀ ń béèrè. Ṣé ẹ lè mu ife tí mò ń mu àbí a lè batisí yín bí a ṣe ń batisí mi?”+
36 Ó sì sọ pé: “Ábà,* Bàbá,+ ohun gbogbo ṣeé ṣe fún ọ; mú ife yìí kúrò lórí mi. Síbẹ̀, kì í ṣe ohun tí èmi fẹ́, àmọ́ ohun tí ìwọ fẹ́.”+