39 Wọ́n sọ fún un pé: “A lè mu ún.” Jésù wá sọ fún wọn pé: “Ẹ máa mu ife tí mò ń mu, a sì máa batisí yín bí a ṣe ń batisí mi.+ 40 Àmọ́ èmi kọ́ ló máa sọ ẹni tó máa jókòó sí ọwọ́ ọ̀tún mi tàbí sí òsì mi, ṣùgbọ́n ó máa wà fún àwọn tí a ti ṣètò rẹ̀ fún.”