Mátíù 12:34 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 34 Ẹ̀yin ọmọ paramọ́lẹ̀,+ báwo lẹ ṣe lè sọ àwọn ohun tó dáa nígbà tó jẹ́ pé ẹni burúkú ni yín? Torí lára ọ̀pọ̀ nǹkan tó wà nínú ọkàn ni ẹnu ń sọ.+
34 Ẹ̀yin ọmọ paramọ́lẹ̀,+ báwo lẹ ṣe lè sọ àwọn ohun tó dáa nígbà tó jẹ́ pé ẹni burúkú ni yín? Torí lára ọ̀pọ̀ nǹkan tó wà nínú ọkàn ni ẹnu ń sọ.+