-
Jòhánù 8:33Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
33 Wọ́n sọ fún un pé: “Ọmọ Ábúráhámù ni wá, a ò sì ṣe ẹrú ẹnikẹ́ni rí. Kí ló dé tí o wá sọ pé, ‘Ẹ máa di òmìnira’?”