Máàkù 11:20, 21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Àmọ́ nígbà tí wọ́n ń kọjá lọ ní àárọ̀ kùtù, wọ́n rí i tí igi ọ̀pọ̀tọ́ náà ti gbẹ láti gbòǹgbò rẹ̀.+ 21 Pétérù rántí rẹ̀, ó sì sọ fún un pé: “Rábì, wò ó! igi ọ̀pọ̀tọ́ tí o gégùn-ún fún ti gbẹ.”+
20 Àmọ́ nígbà tí wọ́n ń kọjá lọ ní àárọ̀ kùtù, wọ́n rí i tí igi ọ̀pọ̀tọ́ náà ti gbẹ láti gbòǹgbò rẹ̀.+ 21 Pétérù rántí rẹ̀, ó sì sọ fún un pé: “Rábì, wò ó! igi ọ̀pọ̀tọ́ tí o gégùn-ún fún ti gbẹ.”+