-
Lúùkù 20:19Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
19 Àwọn akọ̀wé òfin àti àwọn olórí àlùfáà wá ń wá bí ọwọ́ wọn ṣe máa tẹ̀ ẹ́ ní wákàtí yẹn gangan, àmọ́ wọ́n ń bẹ̀rù àwọn èèyàn, torí wọ́n mọ̀ pé àwọn ló ń fi àpèjúwe yìí bá wí.+
-