Mátíù 7:28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 Nígbà tí Jésù sọ àwọn ọ̀rọ̀ yìí tán, ohun tó ṣẹlẹ̀ ni pé bó ṣe ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ ya àwọn èrò náà lẹ́nu,+ Máàkù 11:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Nígbà tí àwọn olórí àlùfáà àti àwọn akọ̀wé òfin gbọ́ èyí, wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí í wá bí wọ́n ṣe máa pa á;+ àmọ́ wọ́n bẹ̀rù rẹ̀, torí pé ẹ̀kọ́ rẹ̀ ya gbogbo àwọn èèyàn náà lẹ́nu.+
28 Nígbà tí Jésù sọ àwọn ọ̀rọ̀ yìí tán, ohun tó ṣẹlẹ̀ ni pé bó ṣe ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ ya àwọn èrò náà lẹ́nu,+
18 Nígbà tí àwọn olórí àlùfáà àti àwọn akọ̀wé òfin gbọ́ èyí, wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí í wá bí wọ́n ṣe máa pa á;+ àmọ́ wọ́n bẹ̀rù rẹ̀, torí pé ẹ̀kọ́ rẹ̀ ya gbogbo àwọn èèyàn náà lẹ́nu.+