Lúùkù 11:46 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 46 Ó wá sọ pé: “Kódà, ẹ̀yin tí ẹ mọ Òfin dunjú gbé, torí pé ẹ̀ ń di àwọn ẹrù tó ṣòroó gbé ru àwọn èèyàn, àmọ́ ẹ̀yin fúnra yín ò fi ọ̀kan nínú àwọn ìka yín kan àwọn ẹrù náà!+
46 Ó wá sọ pé: “Kódà, ẹ̀yin tí ẹ mọ Òfin dunjú gbé, torí pé ẹ̀ ń di àwọn ẹrù tó ṣòroó gbé ru àwọn èèyàn, àmọ́ ẹ̀yin fúnra yín ò fi ọ̀kan nínú àwọn ìka yín kan àwọn ẹrù náà!+