ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Máàkù 12:38, 39
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 38 Bó ṣe ń kọ́ni, ó sọ pé: “Ẹ ṣọ́ra fún àwọn akọ̀wé òfin tí wọ́n fẹ́ máa rìn kiri nínú aṣọ ńlá, tí wọ́n sì fẹ́ kí wọ́n máa kí wọn níbi ọjà,+ 39 wọ́n fẹ́ ìjókòó iwájú* nínú àwọn sínágọ́gù àti ibi tó lọ́lá jù níbi oúnjẹ alẹ́.+

  • Lúùkù 11:43
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 43 Ẹ gbé, ẹ̀yin Farisí, torí ẹ fẹ́ràn ìjókòó iwájú* nínú sínágọ́gù, ẹ sì fẹ́ràn kí wọ́n máa kí yín níbi ọjà!+

  • Lúùkù 14:7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 7 Ó wá sọ àpèjúwe kan fún àwọn èèyàn tí wọ́n pè síbẹ̀, nígbà tó kíyè sí bí wọ́n ṣe ń yan àwọn ibi tó lọ́lá jù lọ fún ara wọn.+ Ó sọ fún wọn pé:

  • Lúùkù 14:10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 10 Àmọ́ tí wọ́n bá pè ọ́, lọ jókòó síbi tó rẹlẹ̀ jù, kó lè jẹ́ pé tí ẹni tó pè ọ́ wá bá dé, ó máa sọ fún ọ pé, ‘Ọ̀rẹ́, lọ síbi tó ga.’ Ìgbà yẹn lo máa wá gbayì níṣojú gbogbo àwọn tí ẹ jọ jẹ́ àlejò.+

  • Lúùkù 20:46
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 46 “Ẹ ṣọ́ra fún àwọn akọ̀wé òfin tí wọ́n fẹ́ràn kí wọ́n máa rìn kiri nínú aṣọ ńlá, tí wọ́n sì fẹ́ràn kí wọ́n máa kí wọn níbi ọjà, wọ́n fẹ́ ìjókòó iwájú* nínú àwọn sínágọ́gù àti ibi tó lọ́lá jù níbi oúnjẹ alẹ́,+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́