Máàkù 1:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Nígbà yẹn, Jésù wá láti Násárẹ́tì ti Gálílì, Jòhánù sì ṣèrìbọmi fún un ní Jọ́dánì.+