Mátíù 6:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Torí náà, tí o bá ń ṣe ìtọrẹ àánú,* má ṣe fun kàkàkí ṣáájú ara rẹ, bí àwọn alágàbàgebè ṣe ń ṣe nínú àwọn sínágọ́gù àti láwọn ojú ọ̀nà, kí àwọn èèyàn lè kan sáárá sí wọn. Lóòótọ́ ni mo sọ fún yín, wọ́n ti gba èrè wọn ní ẹ̀kúnrẹ́rẹ́.
2 Torí náà, tí o bá ń ṣe ìtọrẹ àánú,* má ṣe fun kàkàkí ṣáájú ara rẹ, bí àwọn alágàbàgebè ṣe ń ṣe nínú àwọn sínágọ́gù àti láwọn ojú ọ̀nà, kí àwọn èèyàn lè kan sáárá sí wọn. Lóòótọ́ ni mo sọ fún yín, wọ́n ti gba èrè wọn ní ẹ̀kúnrẹ́rẹ́.