Mátíù 10:28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 Ẹ má bẹ̀rù àwọn tó ń pa ara àmọ́ tí wọn ò lè pa ọkàn;*+ kàkà bẹ́ẹ̀, ẹ bẹ̀rù ẹni tó lè pa ọkàn àti ara run nínú Gẹ̀hẹ́nà.*+ Lúùkù 12:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Ṣùgbọ́n màá fi ẹni tí ẹ máa bẹ̀rù hàn yín: Ẹ bẹ̀rù Ẹni tó jẹ́ pé lẹ́yìn tó bá pani, ó ní àṣẹ láti sọni sínú Gẹ̀hẹ́nà.*+ Àní, mò ń sọ fún yín, Ẹni yìí ni kí ẹ bẹ̀rù.+
28 Ẹ má bẹ̀rù àwọn tó ń pa ara àmọ́ tí wọn ò lè pa ọkàn;*+ kàkà bẹ́ẹ̀, ẹ bẹ̀rù ẹni tó lè pa ọkàn àti ara run nínú Gẹ̀hẹ́nà.*+
5 Ṣùgbọ́n màá fi ẹni tí ẹ máa bẹ̀rù hàn yín: Ẹ bẹ̀rù Ẹni tó jẹ́ pé lẹ́yìn tó bá pani, ó ní àṣẹ láti sọni sínú Gẹ̀hẹ́nà.*+ Àní, mò ń sọ fún yín, Ẹni yìí ni kí ẹ bẹ̀rù.+