Jẹ́nẹ́sísì 4:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Lẹ́yìn náà, Kéènì sọ fún Ébẹ́lì àbúrò rẹ̀ pé: “Jẹ́ ká lọ sí oko.” Nígbà tí wọ́n sì wà nínú oko, Kéènì lu Ébẹ́lì àbúrò rẹ̀, ó sì pa á.+ Jẹ́nẹ́sísì 4:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Ọlọ́run wá sọ pé: “Kí lo ṣe yìí? Tẹ́tí kó o gbọ́ mi! Ẹ̀jẹ̀ àbúrò rẹ ń ké jáde sí mi láti inú ilẹ̀.+ Hébérù 11:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ìgbàgbọ́ mú kí Ébẹ́lì rú ẹbọ tó níye lórí ju ti Kéènì+ lọ sí Ọlọ́run, ìgbàgbọ́ náà sì mú kó rí ẹ̀rí pé ó jẹ́ olódodo, torí Ọlọ́run fọwọ́ sí* àwọn ẹ̀bùn rẹ̀,+ bó tiẹ̀ kú, ó ṣì ń sọ̀rọ̀+ nípasẹ̀ ìgbàgbọ́ rẹ̀.
8 Lẹ́yìn náà, Kéènì sọ fún Ébẹ́lì àbúrò rẹ̀ pé: “Jẹ́ ká lọ sí oko.” Nígbà tí wọ́n sì wà nínú oko, Kéènì lu Ébẹ́lì àbúrò rẹ̀, ó sì pa á.+
10 Ọlọ́run wá sọ pé: “Kí lo ṣe yìí? Tẹ́tí kó o gbọ́ mi! Ẹ̀jẹ̀ àbúrò rẹ ń ké jáde sí mi láti inú ilẹ̀.+
4 Ìgbàgbọ́ mú kí Ébẹ́lì rú ẹbọ tó níye lórí ju ti Kéènì+ lọ sí Ọlọ́run, ìgbàgbọ́ náà sì mú kó rí ẹ̀rí pé ó jẹ́ olódodo, torí Ọlọ́run fọwọ́ sí* àwọn ẹ̀bùn rẹ̀,+ bó tiẹ̀ kú, ó ṣì ń sọ̀rọ̀+ nípasẹ̀ ìgbàgbọ́ rẹ̀.