Sáàmù 118:26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 Ìbùkún ni fún ẹni tó ń bọ̀ ní orúkọ Jèhófà;+À ń bù kún yín látinú ilé Jèhófà.