Mátíù 7:22, 23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Ọ̀pọ̀ máa sọ fún mi ní ọjọ́ yẹn pé: ‘Olúwa, Olúwa,+ ṣebí a fi orúkọ rẹ sọ tẹ́lẹ̀, a fi orúkọ rẹ lé àwọn ẹ̀mí èṣù jáde, a sì fi orúkọ rẹ ṣe ọ̀pọ̀ iṣẹ́ agbára?’+ 23 Àmọ́, màá sọ fún wọn pé: ‘Mi ò mọ̀ yín rí! Ẹ kúrò lọ́dọ̀ mi, ẹ̀yin arúfin!’+ 2 Tẹsalóníkà 2:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Àmọ́ ohun tó mú kí arúfin náà wà níhìn-ín jẹ́ iṣẹ́ ọwọ́ Sátánì+ pẹ̀lú gbogbo iṣẹ́ agbára àti àwọn iṣẹ́ àmì àti iṣẹ́ ìyanu* tó jẹ́ irọ́ +
22 Ọ̀pọ̀ máa sọ fún mi ní ọjọ́ yẹn pé: ‘Olúwa, Olúwa,+ ṣebí a fi orúkọ rẹ sọ tẹ́lẹ̀, a fi orúkọ rẹ lé àwọn ẹ̀mí èṣù jáde, a sì fi orúkọ rẹ ṣe ọ̀pọ̀ iṣẹ́ agbára?’+ 23 Àmọ́, màá sọ fún wọn pé: ‘Mi ò mọ̀ yín rí! Ẹ kúrò lọ́dọ̀ mi, ẹ̀yin arúfin!’+
9 Àmọ́ ohun tó mú kí arúfin náà wà níhìn-ín jẹ́ iṣẹ́ ọwọ́ Sátánì+ pẹ̀lú gbogbo iṣẹ́ agbára àti àwọn iṣẹ́ àmì àti iṣẹ́ ìyanu* tó jẹ́ irọ́ +