Lúùkù 17:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Torí bí mànàmáná ṣe ń kọ láti apá kan ọ̀run dé apá ibòmíì ní ọ̀run, bẹ́ẹ̀ ni Ọmọ èèyàn+ máa rí ní ọjọ́ rẹ̀.+
24 Torí bí mànàmáná ṣe ń kọ láti apá kan ọ̀run dé apá ibòmíì ní ọ̀run, bẹ́ẹ̀ ni Ọmọ èèyàn+ máa rí ní ọjọ́ rẹ̀.+