1 Kíróníkà 2:10, 11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Rámù bí Ámínádábù. Ámínádábù+ bí Náṣónì,+ ìjòyè àwọn ọmọ Júdà. 11 Náṣónì bí Sálímà.+ Sálímà bí Bóásì.+
10 Rámù bí Ámínádábù. Ámínádábù+ bí Náṣónì,+ ìjòyè àwọn ọmọ Júdà. 11 Náṣónì bí Sálímà.+ Sálímà bí Bóásì.+