Máàkù 13:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Ó máa rán àwọn áńgẹ́lì jáde, wọ́n sì máa kó àwọn àyànfẹ́ rẹ̀ jọ láti atẹ́gùn mẹ́rẹ̀ẹ̀rin, láti ìkángun ayé títí dé ìkángun ọ̀run.+
27 Ó máa rán àwọn áńgẹ́lì jáde, wọ́n sì máa kó àwọn àyànfẹ́ rẹ̀ jọ láti atẹ́gùn mẹ́rẹ̀ẹ̀rin, láti ìkángun ayé títí dé ìkángun ọ̀run.+