Máàkù 13:35 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 35 Torí náà, ẹ máa ṣọ́nà, torí pé ẹ ò mọ ìgbà tí baálé ilé náà ń bọ̀,+ bóyá alẹ́ ni àbí ọ̀gànjọ́ òru àbí àfẹ̀mọ́jú* àbí ní àárọ̀ kùtù,+
35 Torí náà, ẹ máa ṣọ́nà, torí pé ẹ ò mọ ìgbà tí baálé ilé náà ń bọ̀,+ bóyá alẹ́ ni àbí ọ̀gànjọ́ òru àbí àfẹ̀mọ́jú* àbí ní àárọ̀ kùtù,+