Mátíù 13:42 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 42 wọ́n sì máa jù wọ́n sínú iná ìléru.+ Ibẹ̀ ni wọ́n á ti máa sunkún, tí wọ́n á sì ti máa payín keke.
42 wọ́n sì máa jù wọ́n sínú iná ìléru.+ Ibẹ̀ ni wọ́n á ti máa sunkún, tí wọ́n á sì ti máa payín keke.