Mátíù 7:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 “Torí náà, gbogbo ẹni tó gbọ́ ọ̀rọ̀ mi yìí, tó sì ṣe é máa dà bí ọkùnrin kan tó ní òye, tó kọ́ ilé rẹ̀ sórí àpáta.+ Mátíù 7:26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 Bákan náà, gbogbo ẹni tó gbọ́ ọ̀rọ̀ mi yìí, tí kò sì ṣe é máa dà bí òmùgọ̀ ọkùnrin tó kọ́ ilé rẹ̀ sórí iyanrìn.+
24 “Torí náà, gbogbo ẹni tó gbọ́ ọ̀rọ̀ mi yìí, tó sì ṣe é máa dà bí ọkùnrin kan tó ní òye, tó kọ́ ilé rẹ̀ sórí àpáta.+
26 Bákan náà, gbogbo ẹni tó gbọ́ ọ̀rọ̀ mi yìí, tí kò sì ṣe é máa dà bí òmùgọ̀ ọkùnrin tó kọ́ ilé rẹ̀ sórí iyanrìn.+