Lúùkù 19:18, 19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Ìkejì wá dé, ó sọ pé, ‘Olúwa, mo fi mínà rẹ jèrè mínà márùn-ún.’+ 19 Ó sọ fún ẹni yìí náà pé, ‘Ìwọ náà, máa bójú tó ìlú márùn-ún.’
18 Ìkejì wá dé, ó sọ pé, ‘Olúwa, mo fi mínà rẹ jèrè mínà márùn-ún.’+ 19 Ó sọ fún ẹni yìí náà pé, ‘Ìwọ náà, máa bójú tó ìlú márùn-ún.’