Hébérù 13:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Ẹ má gbàgbé láti máa ṣe aájò àlejò,*+ torí àwọn kan ti tipa bẹ́ẹ̀ ṣe àwọn áńgẹ́lì lálejò láìmọ̀.+ 3 Jòhánù 5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Ẹni ọ̀wọ́n, ohun tí ò ń ṣe fún àwọn ará, bó tiẹ̀ jẹ́ pé àlejò ni wọ́n jẹ́ sí ọ,+ fi hàn pé o jẹ́ olóòótọ́.
5 Ẹni ọ̀wọ́n, ohun tí ò ń ṣe fún àwọn ará, bó tiẹ̀ jẹ́ pé àlejò ni wọ́n jẹ́ sí ọ,+ fi hàn pé o jẹ́ olóòótọ́.