Máàkù 14:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Torí ìgbà gbogbo ni àwọn aláìní wà láàárín yín,+ ẹ sì lè ṣe ohun rere sí wọn nígbàkigbà tí ẹ bá fẹ́, àmọ́ ìgbà gbogbo kọ́ ni màá wà láàárín yín.+
7 Torí ìgbà gbogbo ni àwọn aláìní wà láàárín yín,+ ẹ sì lè ṣe ohun rere sí wọn nígbàkigbà tí ẹ bá fẹ́, àmọ́ ìgbà gbogbo kọ́ ni màá wà láàárín yín.+