Máàkù 14:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Lóòótọ́ ni mo sọ fún yín, ibikíbi tí a bá ti ń wàásù ìhìn rere náà ní gbogbo ayé,+ wọ́n á máa sọ ohun tí obìnrin yìí ṣe láti fi rántí rẹ̀.”+
9 Lóòótọ́ ni mo sọ fún yín, ibikíbi tí a bá ti ń wàásù ìhìn rere náà ní gbogbo ayé,+ wọ́n á máa sọ ohun tí obìnrin yìí ṣe láti fi rántí rẹ̀.”+