-
Jòhánù 11:57Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
57 Àmọ́ àwọn olórí àlùfáà àti àwọn Farisí ti pàṣẹ pé tí ẹnikẹ́ni bá mọ ibi tí Jésù wà, kó wá sọ, kí wọ́n lè mú un.*