ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Sáàmù 41:9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  9 Kódà, ẹni tó wà ní àlàáfíà pẹ̀lú mi, tí mo fọkàn tán,+

      Ẹni tí a jọ ń jẹun, ti jìn mí lẹ́sẹ̀.*+

  • Máàkù 14:20
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 20 Ó sọ fún wọn pé: “Ọ̀kan nínú ẹ̀yin Méjìlá tí a jọ ń ki ọwọ́ bọ inú abọ́ ni.+

  • Lúùkù 22:21
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 21 “Àmọ́ ẹ wò ó! ọwọ́ èmi àti ẹni tó máa dà mí jọ wà lórí tábìlì.+

  • Jòhánù 13:26
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 26 Jésù dáhùn pé: “Ẹni tí mo bá fún ní búrẹ́dì tí mo kì bọ inú abọ́ ni.”+ Torí náà, lẹ́yìn tó ki búrẹ́dì bọ inú abọ́, ó mú un fún Júdásì, ọmọ Símónì Ìsìkáríọ́tù.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́