1 Kọ́ríńtì 10:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Ife ìbùkún tí a súre sí, ṣebí láti pín nínú ẹ̀jẹ̀ Kristi ni?+ Ìṣù búrẹ́dì tí a bù, ṣebí láti pín nínú ara Kristi ni?+
16 Ife ìbùkún tí a súre sí, ṣebí láti pín nínú ẹ̀jẹ̀ Kristi ni?+ Ìṣù búrẹ́dì tí a bù, ṣebí láti pín nínú ara Kristi ni?+