Mátíù 28:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Kí ẹ tètè lọ sọ fún àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ pé a ti jí i dìde, torí ẹ wò ó! ó ń lọ sí Gálílì ṣáájú yín.+ Ẹ máa rí i níbẹ̀. Ẹ wò ó! Mo ti sọ fún yín.”+ Mátíù 28:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Àmọ́ àwọn ọmọ ẹ̀yìn mọ́kànlá (11) náà lọ sí Gálílì+ lórí òkè tí Jésù ṣètò pé kí wọ́n ti pàdé.+
7 Kí ẹ tètè lọ sọ fún àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ pé a ti jí i dìde, torí ẹ wò ó! ó ń lọ sí Gálílì ṣáájú yín.+ Ẹ máa rí i níbẹ̀. Ẹ wò ó! Mo ti sọ fún yín.”+