ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Máàkù 14:29-31
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 29 Ṣùgbọ́n Pétérù sọ fún un pé: “Tí gbogbo àwọn yòókù bá tiẹ̀ kọsẹ̀, èmi ò ní kọsẹ̀.”+ 30 Ni Jésù bá sọ fún un pé: “Lóòótọ́ ni mo sọ fún ọ pé lónìí, àní, lóru òní yìí, kí àkùkọ tó kọ lẹ́ẹ̀mejì, o máa sẹ́ mi lẹ́ẹ̀mẹta.”+ 31 Àmọ́ ó ń sọ ṣáá pé: “Tó bá tiẹ̀ gba pé kí n kú pẹ̀lú rẹ, ó dájú pé mi ò ní sẹ́ ọ.” Ohun tí gbogbo àwọn yòókù náà bẹ̀rẹ̀ sí í sọ nìyẹn.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́