ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Máàkù 15:11-14
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 11 Àmọ́ àwọn olórí àlùfáà ru àwọn èrò náà sókè pé kí wọ́n ní kó tú Bárábà sílẹ̀ fún àwọn dípò rẹ̀.+ 12 Pílátù tún fún wọn lésì pé: “Kí wá ni kí n ṣe sí ẹni tí ẹ̀ ń pè ní Ọba Àwọn Júù?”+ 13 Wọ́n ké jáde lẹ́ẹ̀kan sí i pé: “Kàn án mọ́gi!”*+ 14 Àmọ́ Pílátù sọ fún wọn pé: “Kí ló dé? Nǹkan burúkú wo ló ṣe?” Síbẹ̀, wọ́n túbọ̀ kígbe pé: “Kàn án mọ́gi!”+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́